Isa 32:17
Isa 32:17 Yoruba Bible (YCE)
Àyọrísí òdodo yóo sì jẹ́ alaafia, ìgbẹ̀yìn rẹ̀ yóo sì jẹ́ ìbàlẹ̀ àyà wa, ati igbẹkẹle OLUWA títí lae.
Pín
Kà Isa 32Isa 32:17 Bibeli Mimọ (YBCV)
Iṣẹ ododo yio si jẹ alafia, ati eso ododo yio jẹ idakẹjẹ on ãbo titi lai.
Pín
Kà Isa 32