Oluwa, ṣãnu fun wa; awa ti duro dè ọ: iwọ mã ṣe apá wọn li òròwúrọ̀ ani igbala wa nigba ipọnju.
Ṣàánú wa OLUWA, ìwọ ni a dúró tí à ń wò. Máa ràn wá lọ́wọ́ lojoojumọ, sì máa jẹ́ olùgbàlà wa nígbà ìṣòro.
OLúWA ṣàánú fún wa àwa ń ṣàfẹ́rí i rẹ. Máa jẹ́ agbára wa ní òròòwúrọ̀ ìgbàlà wa ní àsìkò ìpọ́njú.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò