Isa 43:20-21
Isa 43:20-21 Yoruba Bible (YCE)
Àwọn ẹranko ìgbẹ́ yóo máa yìn mí lógo, ati àwọn ọ̀fàfà ati ògòǹgò; nítorí pé mo ti ṣe odò ńlá fún wọn ninu aṣálẹ̀, kí àwọn àyànfẹ́ mi lè máa rí omi mu: Àwọn tí mo fọwọ́ mi dá fún ara mi, kí wọ́n lè kéde ògo mi.
Pín
Kà Isa 43