Kiyesi i, iranṣẹ mi yio fi oye bá ni lò; a o gbe e ga, a o si gbe e leke, on o si ga gidigidi.
Wò ó! Iranṣẹ mi yóo ṣe àṣeyọrí a óo gbé e ga, a óo gbé e lékè; yóo sì di ẹni gíga
Kíyèsi i, ìránṣẹ́ mi yóò hùwà ọlọ́gbọ́n; òun ni a ó gbé sókè tí a ó sì gbéga a ó sì gbé e lékè gidigidi.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò