Isa 60:4
Isa 60:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
“Gbé ojú rẹ sókè, kí o sì wò: Gbogbo wọn ṣa ara jọ pọ̀, wọ́n sì wá sọ́dọ̀ rẹ; àwọn ọmọ rẹ ọkùnrin yóò wá láti ọ̀nà jíjìn, àwọn ọmọ rẹ obìnrin ni a ó tọ́jú ní ẹ̀gbẹ́ rẹ.
Pín
Kà Isa 60