Isa 63:9
Isa 63:9 Yoruba Bible (YCE)
Ninu gbogbo ìyà tí wọ́n jẹ, òun pẹlu wọn ni, angẹli iwájú rẹ̀ sì gbà wọ́n là. Nítorí ìfẹ́ ati àánú rẹ̀, ó rà wọ́n pada. Ó fà wọ́n sókè, ó sì gbé wọn ní gbogbo ìgbà àtijọ́.
Pín
Kà Isa 63Ninu gbogbo ìyà tí wọ́n jẹ, òun pẹlu wọn ni, angẹli iwájú rẹ̀ sì gbà wọ́n là. Nítorí ìfẹ́ ati àánú rẹ̀, ó rà wọ́n pada. Ó fà wọ́n sókè, ó sì gbé wọn ní gbogbo ìgbà àtijọ́.