Angeli OLUWA na si farahàn a, o si wi fun u pe, OLUWA wà pẹlu rẹ, iwọ ọkunrin alagbara.
Nígbà tí angẹli OLúWA fi ara han Gideoni, ó wí fún un pé, “OLúWA wà pẹ̀lú rẹ, akọni ológun.”
ni angẹli OLUWA náà yọ sí i, ó sì wí fún un pé, “OLUWA wà pẹlu rẹ, ìwọ akikanju ati alágbára ọkunrin.”
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò