Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Jer 16:20YBCV(Bibeli Mimọ)
Enia lè ma dá ọlọrun fun ara rẹ̀: nitori awọn wọnyi kì iṣe ọlọrun?
Pín
Jer 16YBCVJer 16:20BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣé àwọn ènìyàn lè dá Ọlọ́run fún ara wọn bí? Bẹ́ẹ̀ ni, ṣùgbọ́n àwọn wọ̀nyí kì í ṣe Ọlọ́run.”
Pín
Jer 16BMYOJer 16:20YCE(Yoruba Bible)
Ṣé eniyan lè fi ọwọ́ ara rẹ̀ ṣẹ̀dá ọlọrun? Irú ọlọrun bẹ́ẹ̀ kì í ṣe ọlọrun rárá.”
Pín
Jer 16YCE