Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Jer 16:21YBCV(Bibeli Mimọ)

Nitorina, sa wò o, emi o mu ki nwọn ki o mọ̀, lẹ̃kan yi, emi o si mu ki nwọn ki o mọ̀ ọwọ mi ati ipa mi; nwọn o si mọ̀ pe, orukọ mi ni JEHOFA.

Jer 16:21BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

“Nítorí náà, Èmi yóò kọ́ wọn ní àkókò yìí, Èmi yóò kọ́ wọn pẹ̀lú agbára àti títóbi mi. Nígbà náà ni wọn ó mọ pé orúkọ mi ní OLúWA.

Jer 16:21YCE(Yoruba Bible)

OLUWA ní, “Nítorí náà, wò ó, n óo jẹ́ kí wọn mọ̀; àní sẹ́, n óo jẹ́ kí wọ́n mọ agbára ati ipá mi; wọn yóo sì mọ̀ pé orúkọ mi ni OLUWA.”