Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Jer 17:10YBCV(Bibeli Mimọ)
Emi, Oluwa, ni iwá awari ọkàn enia, emi ni ndan inu wò, ani lati fi fun olukuluku gẹgẹ bi ọ̀na rẹ̀, ati gẹgẹ bi eso iṣe rẹ̀.
Pín
Jer 17YBCVJer 17:10BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Èmi OLúWA ń wo ọkàn àti èrò inú ọmọ ènìyàn, láti san èrè iṣẹ́ rẹ̀ fún un gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà rẹ̀, àti gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.”
Pín
Jer 17BMYOJer 17:10YCE(Yoruba Bible)
Èmi OLUWA ni èmi máa ń wádìí èrò eniyan, tí èmi sì máa ń yẹ ọkàn eniyan wò, láti san án fún olukuluku gẹ́gẹ́ bí ìṣe rẹ̀, ati gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”
Pín
Jer 17YCE