Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Jer 17:14YBCV(Bibeli Mimọ)

Wò mi sàn, Oluwa, emi o si sàn! gbà mi là, emi o si là, nitori iwọ ni iyìn mi!

Jer 17:14BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Wò mí sàn OLúWA, èmi yóò di ẹni ìwòsàn, gbà mí là, èmi yóò di ẹni ìgbàlà, nítorí ìwọ ni ìyìn mi.

Jer 17:14YCE(Yoruba Bible)

Wò mí sàn, OLUWA, ara mi yóo sì dá, gbà mí, n óo sì bọ́ ninu ewu. Nítorí pé ìwọ ni mò ń yìn.