Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Jer 20:13YBCV(Bibeli Mimọ)

Ẹ kọrin si Oluwa, ẹ yìn Oluwa, nitoriti o ti gbà ọkàn talaka kuro lọwọ awọn oluṣe buburu.

Jer 20:13BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Kọrin sí OLúWA! Fi ìyìn fún OLúWA! Ó gba ẹ̀mí àwọn aláìní lọ́wọ́ àwọn ẹni búburú.

Jer 20:13YCE(Yoruba Bible)

Ẹ kọrin sí OLUWA, ẹ yin OLUWA. Nítorí pé ó gba ẹ̀mí aláìní sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn aṣebi.