Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Jer 21:14YBCV(Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn emi o jẹ nyin niya gẹgẹ bi eso iṣe nyin, li Oluwa wi; emi o si da iná ninu igbo rẹ ki o le jo gbogbo agbegbe rẹ.
Pín
Jer 21YBCVJer 21:14BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò jẹ ọ ní ìyà gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ ni OLúWA wí. Èmi yóò mú kí iná jó ilé rẹ̀; yóò si jó gbogbo ohun tí ó wà ní àyíká rẹ.’ ”
Pín
Jer 21BMYOJer 21:14YCE(Yoruba Bible)
N óo jẹ yín níyà gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọwọ́ yín; èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀. N óo dáná sun igbó yín, yóo sì jó gbogbo ohun tí ó wà ní agbègbè yín ní àjórun.”
Pín
Jer 21YCE