Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Jer 24:7YBCV(Bibeli Mimọ)
Emi o si fun wọn li ọkàn lati mọ̀ mi, pe, Emi li Oluwa, nwọn o si jẹ enia mi, emi o si jẹ Ọlọrun wọn, nitoripe nwọn o fi gbogbo ọkàn wọn yipada si mi.
Pín
Jer 24YBCVJer 24:7BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò fún wọn ní ọkàn láti mọ̀ mí pé, “Èmi ni OLúWA.” Wọn yóò jẹ́ ènìyàn mi; Èmi ni yóò sì jẹ́ Ọlọ́run wọn; nítorí pé wọn yóò padà sọ́dọ̀ mi pẹ̀lú gbogbo ọkàn wọn.
Pín
Jer 24BMYOJer 24:7YCE(Yoruba Bible)
n óo sì fún wọn ní òye láti mọ̀ pé èmi ni OLUWA. Wọn yóo jẹ́ eniyan mi, èmi náà óo sì jẹ́ Ọlọrun wọn; nítorí tí wọn yóo fi tọkàntọkàn yipada sí mi.”
Pín
Jer 24YCE