Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Jer 27:5YBCV(Bibeli Mimọ)
Emi ti dá aiye, enia ati ẹranko ti o wà lori ilẹ aiye, nipa agbara nla mi, ati nipa ọwọ ninà mi, emi si fi i fun ẹnikẹni ti o wù mi.
Pín
Jer 27YBCVJer 27:5BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Pẹ̀lú agbára ńlá mi àti ọwọ́ nínà mi ni Èmi dá ayé, ènìyàn àti ẹranko tí ó wà lórí ilẹ̀ ayé, mo sì fún ẹni tí ó wu ọkàn mi.
Pín
Jer 27BMYOJer 27:5YCE(Yoruba Bible)
òun ni òun fi agbára ńlá òun dá ayé: ati eniyan ati ẹranko tí wọ́n wà lórí ilẹ̀; ẹni tí ó bá tọ́ lójú òun ni òun óo sì fi wọ́n fún.
Pín
Jer 27YCE