Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Jer 28:17YBCV(Bibeli Mimọ)

Bẹ̃ni Hananiah woli si kú li ọdun na li oṣu keje.

Jer 28:17BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Ní oṣù keje ọdún yìí ni Hananiah wòlíì kú.

Jer 28:17YCE(Yoruba Bible)

Ní ọdún náà gan-an ní oṣù keje, ni Hananaya wolii kú.