Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Jer 28:9YBCV(Bibeli Mimọ)
Woli nì ti o sọ asọtẹlẹ alafia, bi ọ̀rọ woli na ba ṣẹ, nigbana ni a o mọ̀ woli na pe, Oluwa rán a nitõtọ.
Pín
Jer 28YBCVJer 28:9BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n, àwọn wòlíì tí ó ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ àlàáfíà ni a mọ̀ gẹ́gẹ́ bí wòlíì olóòtítọ́ tí OLúWA rán, tí àsọtẹ́lẹ̀ rẹ bá wá sí ìmúṣẹ.”
Pín
Jer 28BMYOJer 28:9YCE(Yoruba Bible)
Wolii tí ó bá fẹ́ sọ àsọtẹ́lẹ̀ pé alaafia yóo wà, nígbà tí ọ̀rọ̀ wolii náà bá ṣẹ ni a óo mọ̀ pé OLUWA ni ó rán an níṣẹ́ nítòótọ́.”
Pín
Jer 28YCE