Yipada, ẹnyin ọmọ apẹhinda, emi o si wò ipẹhinda nyin sàn; Sa wò o, awa tọ̀ ọ wá, nitori iwọ li Oluwa Ọlọrun wa!
Ẹ yipada, ẹ̀yin alaiṣootọ ọmọ, n óo mú aiṣootọ yín kúrò. “Wò wá! A wá sọ́dọ̀ rẹ, nítorí ìwọ ni OLUWA Ọlọrun wa.
“Padà, ẹ̀yin ènìyàn aláìnígbàgbọ́, Èmi ó wo ìpadàsẹ́yìn kúrò ní ọ̀nà títọ́ rẹ sàn.” “Bẹ́ẹ̀, ni a ó wá sọ́dọ̀ rẹ nítorí ìwọ ni OLúWA Ọlọ́run wa.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò