Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Jer 30:22YBCV(Bibeli Mimọ)

Ẹnyin o si jẹ enia mi, emi o si jẹ Ọlọrun nyin.

Jer 30:22BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

‘Nítorí náà, ẹ̀yin yóò jẹ́ ènìyàn mi, èmi yóò sì jẹ́ Ọlọ́run yín.’ ”

Jer 30:22YCE(Yoruba Bible)

Ẹ óo jẹ́ eniyan mi, n óo sì jẹ́ Ọlọrun yín.”