Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Jer 44:23YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitori ti ẹnyin ti sun turari, ati nitori ti ẹnyin ṣẹ̀ si Oluwa, ti ẹnyin kò gbà ohùn Oluwa gbọ́, ti ẹ kò rin ninu ofin rẹ̀, ati ninu ilana rẹ̀, ati ninu ọ̀rọ ẹri rẹ̀; nitorina ni ibi yi ṣe de si nyin, bi o ti ri li oni yi.
Pín
Jer 44YBCVJer 44:23BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pé ẹ ti sun ẹbọ, tí ẹ sì ti ṣẹ̀ sí OLúWA àti pé ẹ kò gbọ́rọ̀ sí i lẹ́nu, àti pé ẹ kò sì tẹ̀lé òfin rẹ̀ àti àwọn àṣẹ. Ibi náà yóò wá sórí rẹ àti bí o ṣe rí i.”
Pín
Jer 44BMYOJer 44:23YCE(Yoruba Bible)
Ìdí tí èyí fi ṣẹlẹ̀ si yín ni pé ẹ sun turari, ẹ sì dẹ́ṣẹ̀ sí OLUWA. Ẹ kò fetí sí ọ̀rọ̀ OLUWA, ẹ kò pa òfin, ati ìlànà rẹ̀ mọ́.”
Pín
Jer 44YCE