Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Jer 50:34YBCV(Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn Olurapada wọn lagbara; Oluwa awọn ọmọ-ogun li orukọ rẹ̀: ni jijà yio gba ijà wọn jà! ki o le mu ilẹ na simi, ki o si mu awọn olugbe Babeli wariri.
Pín
Jer 50YBCVJer 50:34BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Síbẹ̀, Olùràpadà wọn, Alágbára, OLúWA Ọlọ́run Alágbára ni orúkọ rẹ̀. Yóò sì gbe ìjà wọn jà, kí ó ba à lè mú wọn wá sinmi ní ilẹ̀ náà; ṣùgbọ́n kò sí ìsinmi fún àwọn tí ó ń gbé Babeli.
Pín
Jer 50BMYOJer 50:34YCE(Yoruba Bible)
Ṣugbọn alágbára ni Olùràpadà wọn, OLUWA àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀. Dájúdájú, yóo jà fún wọn, kí ó lè fún ayé ní ìsinmi, ṣugbọn kí ìdààmú lè bá àwọn ará Babiloni.”
Pín
Jer 50YCE