Iwọ o si wi fun wọn pe, Bayi li Oluwa wi; enia le ṣubu li aidide mọ? tabi enia le pada, ki o má tun yipada mọ?
OLUWA ní kí n sọ fún wọn pé, “Ṣé bí eniyan bá ṣubú kì í tún dìde mọ́? Àbí bí eniyan bá ṣìnà, kì í pada mọ́?
“Wí fún wọn pé, ‘Èyí ni ohun tí OLúWA wí: “ ‘Bí ènìyàn bá ṣubú lulẹ̀ wọn kì í padà dìde bí? Nígbà tí ènìyàn bá yà kúrò ní ọ̀nà rẹ, kì í yí padà bí?
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò