Joh 3:17
Joh 3:17 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori Ọlọrun kò rán Ọmọ rẹ̀ si aiye lati da araiye lẹjọ; ṣugbọn ki a le ti ipasẹ rẹ̀ gbà araiye là.
Pín
Kà Joh 3Joh 3:17 Yoruba Bible (YCE)
Nítorí Ọlọrun kò rán Ọmọ rẹ̀ wá sí ayé láti dá aráyé lẹ́bi bíkòṣe pé kí aráyé lè ti ipasẹ̀ rẹ̀ ní ìgbàlà.
Pín
Kà Joh 3