Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Joel 3:10YBCV(Bibeli Mimọ)
Ẹ fi irin ọkọ́ itulẹ̀ nyin rọ idà, ati dojé nyin rọ ọkọ̀: jẹ ki alailera wi pe, Ara mi le koko.
Pín
Joel 3YBCVJoel 3:10BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ fi irin ìtulẹ̀ yín rọ idà, àti dòjé yín rọ ọ̀kọ̀. Jẹ́ kí aláìlera wí pé, “Ara mi le koko.”
Pín
Joel 3BMYOJoel 3:10YCE(Yoruba Bible)
Ẹ fi irin ọkọ́ yín rọ idà, ẹ fi dòjé yín rọ ọ̀kọ̀, kí àwọn tí wọn kò lágbára wí pé, “Ọmọ ogun ni mí.”
Pín
Joel 3YCE