Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Joṣ 21:45YBCV(Bibeli Mimọ)
Ohunkohun kò tase ninu ohun rere ti OLUWA ti sọ fun ile Israeli; gbogbo rẹ̀ li o ṣẹ.
Pín
Joṣ 21YBCVJoṣ 21:45BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kò sí ọ̀kan nínú ìlérí rere tí OLúWA ṣe fún ilé Israẹli tí ó kùnà, gbogbo rẹ̀ ni ó ṣe.
Pín
Joṣ 21BMYOJoṣ 21:45YCE(Yoruba Bible)
Ninu gbogbo ìlérí dáradára tí OLUWA ṣe fún ilé Israẹli kò sí èyí tí kò mú ṣẹ; gbogbo wọn patapata ni ó mú ṣẹ.
Pín
Joṣ 21YCE