Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Joṣ 23:10YBCV(Bibeli Mimọ)

Ọkunrin kan ninu nyin yio lé ẹgbẹrun: nitoripe OLUWA Ọlọrun nyin, on li ẹniti njà fun nyin, gẹgẹ bi o ti sọ fun nyin.

Joṣ 23:10BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Ọ̀kan nínú yín lé ẹgbẹ̀rún (1,000) ọ̀tá, nítorí tí OLúWA Ọlọ́run yín jà fún yín gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe ìlérí.

Joṣ 23:10YCE(Yoruba Bible)

Ẹyọ ẹnìkan ṣoṣo ninu yín ni ó ń bá ẹgbẹrun eniyan jà, nítorí pé OLUWA Ọlọrun yín ni ó ń jà fun yín, gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣèlérí fun yín.