Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Joṣ 23:11YBCV(Bibeli Mimọ)

Nitorina ẹ kiyesara nyin gidigidi, ki ẹ fẹ́ OLUWA Ọlọrun nyin.

Joṣ 23:11BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ ṣọ́ra gidigidi láti fẹ́ràn OLúWA Ọlọ́run yín.

Joṣ 23:11YCE(Yoruba Bible)

Nítorí náà, ẹ ṣọ́ra, kí ẹ sì fẹ́ràn OLUWA Ọlọrun yín.