Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Joṣ 24:16YBCV(Bibeli Mimọ)
Awọn enia na dahùn, nwọn si wipe, Ki a má ri ti awa o fi kọ̀ OLUWA silẹ, lati sìn oriṣa
Pín
Joṣ 24YBCVJoṣ 24:16BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ènìyàn sì dáhùn pé, “Kí a má ri tí àwa yóò fi kọ OLúWA sílẹ̀ láti sin òrìṣà!
Pín
Joṣ 24BMYOJoṣ 24:16YCE(Yoruba Bible)
Nígbà náà ni àwọn eniyan náà dáhùn, wọ́n ní, “Kí á má rí i pé a kọ OLUWA sílẹ̀, a sì ń bọ oriṣa.
Pín
Joṣ 24YCE