Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Joṣ 9:14YBCV(Bibeli Mimọ)
Awọn ọkunrin si gbà ninu onjẹ wọn, nwọn kò si bère li ẹnu OLUWA.
Pín
Joṣ 9YBCVJoṣ 9:14BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọkùnrin Israẹli sì yẹ oúnjẹ wọn wò, wọn kò sì wádìí ní ọwọ́ OLúWA.
Pín
Joṣ 9BMYOJoṣ 9:14YCE(Yoruba Bible)
Àwọn ọmọ Israẹli bá wọn jẹ ninu oúnjẹ wọn, wọn kò sì bèèrè ìtọ́sọ́nà lọ́dọ̀ OLUWA.
Pín
Joṣ 9YCE