Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Ẹk. Jer 1:20YBCV(Bibeli Mimọ)

Wò o, Oluwa: nitoriti emi wà ninu ipọnju: inu mi nhó; ọkàn mi yipada ninu mi; nitoriti emi ti ṣọ̀tẹ gidigidi: lode, idà sọni di alailọmọ, ni ile, o dabi ikú!

Ẹk. Jer 1:20BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

“OLúWA, wò ó, bí mo ti wà nínú ìnira! Tí mo sì ń jẹ̀rora nínú mi, ìdààmú dé bá ọkàn mi nítorí pé a ti ṣọ̀tẹ̀ sí mi gidigidi. Ní gbangba ni idà ń parun; ikú wà nínú ilé pẹ̀lú.

Ẹk. Jer 1:20YCE(Yoruba Bible)

“Bojúwò mí, OLUWA, nítorí mo wà ninu ìpọ́njú, ọkàn mi ti dàrú, inú mi bàjẹ́, nítorí pé mo ti hùwà ọ̀tẹ̀ lọpọlọpọ. Níta gbangba, ogun ń pa mí lọ́mọ; bákan náà ni ikú ń bẹ ninu ilé.