Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Ẹk. Jer 3:24YBCV(Bibeli Mimọ)

Oluwa ni ipin mi, bẹ̃li ọkàn mi wi; nitorina ni emi ṣe reti ninu rẹ̀.

Ẹk. Jer 3:24BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Mo wí fún ara mi, ìpín mi ni OLúWA; nítorí náà èmi yóò dúró dè ọ́.

Ẹk. Jer 3:24YCE(Yoruba Bible)

Ọkàn mi wí pé, “OLUWA ni ìpín mi, nítorí náà lọ́dọ̀ rẹ̀ ni ìrètí mi wà.”