Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Ẹk. Jer 3:25YBCV(Bibeli Mimọ)

Oluwa ṣe rere fun gbogbo ẹniti o duro dè e, fun ọkàn ti o ṣafẹri rẹ̀.

Ẹk. Jer 3:25BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Dídára ni OLúWA fún àwọn tí ó ní ìrètí nínú rẹ̀, sí àwọn tí ó ń wá a.

Ẹk. Jer 3:25YCE(Yoruba Bible)

OLUWA a máa ṣe oore fún àwọn tí wọn dúró dè é, tí wọn sì ń wá ojurere rẹ̀.