Lef 10:2 - Compare All Versions

Lef 10:2 YBCV (Bibeli Mimọ)

Iná si ti ọdọ OLUWA jade, o si run wọn, nwọn si kú niwaju OLUWA.

Lef 10:2 YCE (Yoruba Bible)

OLUWA bá rán iná kan jáde, iná náà jó wọn pa, wọ́n sì kú níwájú OLUWA.

Lef 10:2 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Torí èyí, iná jáde láti ọ̀dọ̀ OLúWA, ó sì jó wọn pa, wọ́n sì kú níwájú OLúWA.