Lef 19:18 - Compare All Versions
Lef 19:18 YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ kò gbọdọ gbẹsan, bẹ̃ni ki o máṣe ṣe ikùnsinu si awọn ọmọ enia rẹ, ṣugbọn ki iwọ ki o fẹ́ ẹnikeji rẹ bi ara rẹ: Emi li OLUWA.
Pín
Lef 19 YBCVLef 19:18 YCE (Yoruba Bible)
Ẹ kò gbọdọ̀ gbẹ̀san, tabi kí ẹ di ọmọ eniyan yín sinu, ṣugbọn ẹ níláti fẹ́ràn ọmọnikeji yín gẹ́gẹ́ bí ara yín. Èmi ni OLUWA.
Pín
Lef 19 YCELef 19:18 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ gbẹ̀san: má sì ṣe bínú sí èyíkéyìí nínú àwọn ènìyàn rẹ. Ṣùgbọ́n, kí ìwọ kí ó fẹ́ ẹnìkejì rẹ bí ara rẹ. Èmi ni OLúWA.
Pín
Lef 19 BMYO