Lef 19:2 - Compare All Versions

Lef 19:2 YBCV (Bibeli Mimọ)

Sọ fun gbogbo ijọ awọn ọmọ Israeli, ki o si wi fun wọn pe, Ki ẹnyin ki o jẹ́ mimọ́: nitoripe Emi OLUWA Ọlọrun nyin jẹ́ mimọ́.

Lef 19:2 YCE (Yoruba Bible)

pé kí ó sọ fún ìjọ eniyan Israẹli pé “Ẹ jẹ́ mímọ́, nítorí pé, mímọ́ ni èmi OLUWA Ọlọrun yín.

Lef 19:2 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

“Bá gbogbo àpéjọpọ̀ àwọn ọmọ Israẹli sọ̀rọ̀, sì wí fún wọn pé, ‘Ẹ jẹ́ mímọ́ nítorí Èmi OLúWA Ọlọ́run yín jẹ́ mímọ́.