Lef 26:10 - Compare All Versions
Lef 26:10 YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹnyin o si ma jẹ ohun isigbẹ, ẹnyin o si ma kó ohun ẹgbẹ jade nitori ohun titun.
Pín
Lef 26 YBCVLef 26:10 YCE (Yoruba Bible)
Ẹ óo jẹ àwọn nǹkan oko tí ẹ kó sí inú abà fún ọjọ́ pípẹ́, ẹ óo sì máa ru ìyókù wọn dànù kí ẹ lè rí ààyè kó tuntun sí.
Pín
Lef 26 YCELef 26:10 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn èrè oko yín yóò pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ tí ẹ̀yin ó máa jẹ èrè ọdún tí ó kọjá, ẹ̀yin ó sì kó wọn jáde, kí ẹ̀yin lè rí ààyè kó tuntun sí.
Pín
Lef 26 BMYO