Lef 26:8 - Compare All Versions
Lef 26:8 YBCV (Bibeli Mimọ)
Marun ninu nyin yio si lé ọgọrun, ọgọrun ninu nyin yio si lé ẹgbarun: awọn ọtá nyin yio si ti ipa idà ṣubu niwaju nyin.
Pín
Lef 26 YBCVLef 26:8 YCE (Yoruba Bible)
Marun-un ninu yín yóo lé ọgọrun-un ọ̀tá sẹ́yìn, ọgọrun-un ninu yín yóo sì lé ẹgbaarun (10,000) àwọn ọ̀tá yín sẹ́yìn, idà ni ẹ óo fi máa pa wọ́n.
Pín
Lef 26 YCELef 26:8 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn márùn-ún péré nínú yín yóò máa ṣẹ́gun ọgọ́rùn-ún ènìyàn, àwọn ọgọ́rùn-ún yóò sì máa ṣẹ́gun ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000), àwọn ọ̀tá yín yóò tipa idà kú níwájú yín.
Pín
Lef 26 BMYO