Lef 9:24 - Compare All Versions
Lef 9:24 YBCV (Bibeli Mimọ)
Iná kan si ti ọdọ OLUWA jade wá, o si jó ẹbọ sisun ati ọrá ori pẹpẹ na; nigbati gbogbo awọn enia ri i, nwọn hó kùhu, nwọn si dojubolẹ.
Pín
Lef 9 YBCVLef 9:24 YCE (Yoruba Bible)
Lójijì, iná ṣẹ́ láti ọ̀dọ̀ OLUWA wá, ó jó ẹbọ sísun náà, ati ọ̀rá tí ó wà lórí pẹpẹ. Nígbà tí gbogbo àwọn eniyan rí i, wọ́n kígbe sókè, wọ́n sì dojúbolẹ̀.
Pín
Lef 9 YCELef 9:24 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Iná sì jáde láti ọ̀dọ̀ OLúWA, ó sì jó ẹbọ sísun àti ọ̀rá orí pẹpẹ. Nígbà tí gbogbo ènìyàn sì rí èyí wọ́n hó ìhó ayọ̀, wọ́n sì dojúbolẹ̀.
Pín
Lef 9 BMYO