Luk 11:4
Luk 11:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Kí o sì dárí ẹ̀ṣẹ̀ wa jì wá; nítorí àwa tìkára wa pẹ̀lú a máa dáríjì olúkúlùkù ẹni tí ó jẹ wá ní gbèsè, Má sì fà wá sínú ìdánwò, ṣùgbọ́n gbà wá lọ́wọ́ ẹni búburú ni.’ ”
Pín
Kà Luk 11