Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 11:12YBCV(Bibeli Mimọ)
Lati igba ọjọ Johanu Baptisti wá, titi o fi di isisiyi ni ijọba ọrun di ifi agbara wọ, awọn alagbara si fi ipá gbà a.
Pín
Mat 11YBCVMat 11:12BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Láti ìgbà ọjọ́ Johanu onítẹ̀bọmi títí di àkókò yìí ni ìjọba ọ̀run ti di à fi agbára wọ̀, àwọn alágbára ló ń fi ipá gbà á.
Pín
Mat 11BMYOMat 11:12YCE(Yoruba Bible)
Láti àkókò tí Johanu Onítẹ̀bọmi ti bẹ̀rẹ̀ sí waasu títí di ìsinsìnyìí ni àwọn alágbára ti gbógun ti ìjọba ọ̀run, wọ́n sì fẹ́ fi ipá gbà á.
Pín
Mat 11YCE