Mat 27:51-52
Mat 27:51-52 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Lójúkan náà aṣọ ìkélé tẹmpili fàya, láti òkè dé ìsàlẹ̀. Ilẹ̀ sì mì tìtì. Àwọn àpáta sì sán. Àwọn isà òkú sì ṣí sílẹ̀. Ọ̀pọ̀ òkú àwọn ẹni mímọ́ tí ó ti sùn sì tún jíǹde.
Pín
Kà Mat 27