Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 6:21YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitori nibiti iṣura nyin bá gbé wà, nibẹ̀ li ọkàn nyin yio gbé wà pẹlu.
Pín
Mat 6YBCVMat 6:21BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ibi tí ìṣúra yín bá wà níbẹ̀ náà ni ọkàn yín yóò wà pẹ̀lú.
Pín
Mat 6BMYO