Mik 5:4 - Compare All Versions
Mik 5:4 YBCV (Bibeli Mimọ)
On o si duro yio si ma jẹ̀ li agbara Oluwa, ni ọlanla orukọ Oluwa Ọlọrun rẹ̀; nwọn o si wà, nitori nisisiyi ni on o tobi titi de opin aiye.
Pín
Mik 5 YBCVMik 5:4 YCE (Yoruba Bible)
Yóo dìde, yóo sì mójútó àwọn eniyan rẹ̀ pẹlu agbára OLUWA, àní, ninu ọláńlá orúkọ OLUWA Ọlọrun rẹ̀. Wọn óo máa gbé ní àìléwu, nítorí yóo di ẹni ńlá jákèjádò gbogbo ayé.
Pín
Mik 5 YCEMik 5:4 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Òun yóò sì dúró, yóò sì máa ṣe olùṣọ́-àgùntàn àwọn agbo ẹran rẹ̀ ní agbára OLúWA, ní ọláńlá orúkọ OLúWA Ọlọ́run rẹ̀. Wọn yóò sì wà láìléwu, nítorí nísinsin yìí ni títóbi rẹ yóò sì dé òpin ayé.
Pín
Mik 5 BMYO