Mak 3:24-25
Mak 3:24-25 Yoruba Bible (YCE)
Bí ìjọba kan náà bá gbé ogun ti ara rẹ̀, ìjọba náà yóo parun. Bí àwọn ará ilé kan náà bá ń bá ara wọn jà, ilé náà kò lè fi ìdí múlẹ̀.
Pín
Kà Mak 3Bí ìjọba kan náà bá gbé ogun ti ara rẹ̀, ìjọba náà yóo parun. Bí àwọn ará ilé kan náà bá ń bá ara wọn jà, ilé náà kò lè fi ìdí múlẹ̀.