Num 22:27
Num 22:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Nígbà tí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rí angẹli OLúWA, ó sì jókòó ní abẹ́ Balaamu, inú sì bí i tó sì nà án pẹ̀lú ọ̀pá rẹ̀.
Pín
Kà Num 22Nígbà tí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rí angẹli OLúWA, ó sì jókòó ní abẹ́ Balaamu, inú sì bí i tó sì nà án pẹ̀lú ọ̀pá rẹ̀.