Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Num 23:20YBCV(Bibeli Mimọ)
Kiyesi i, emi gbà aṣẹ ati sure: on si ti sure, emi kò si le yì i.
Pín
Num 23YBCVNum 23:20BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi gba àṣẹ láti bùkún; Ó sì ti bùkún, èmi kò sì lè yípadà.
Pín
Num 23BMYONum 23:20YCE(Yoruba Bible)
OLUWA ti sọ fún mi pé kí n bukun wọn, Ọlọrun pàápàá ti bukun wọn, èmi kò lè mú ibukun náà kúrò.
Pín
Num 23YCE