Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Oba 1:4YBCV(Bibeli Mimọ)

Bi iwọ tilẹ gbe ara rẹ ga bi idì, ati bi iwọ tilẹ tẹ́ itẹ rẹ sãrin awọn irawọ, lati ibẹ li emi o ti sọ̀ ọ kalẹ, ni Oluwa wi.

Oba 1:4BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Bí ìwọ tilẹ̀ gbé ara rẹ ga bí ẹyẹ idì, bí ìwọ tilẹ̀ tẹ́ ìtẹ́ rẹ sí àárín àwọn ìràwọ̀, láti ibẹ̀ ni èmi yóò ti sọ̀ ọ kalẹ̀,” ni OLúWA wí.

Oba 1:4YCE(Yoruba Bible)

Bí o tilẹ̀ fò lọ sókè bí ẹyẹ idì, tí ó tẹ́ ìtẹ́ rẹ̀ sí ààrin àwọn ìràwọ̀, láti òkè náà ni n óo ti fà ọ́ lulẹ̀. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.