Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Owe 16:22YBCV(Bibeli Mimọ)
Oye li orisun ìye fun ẹniti o ni i: ṣugbọn ẹkọ́ aṣiwère ni iwère.
Pín
Owe 16YBCVOwe 16:22BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Òye jẹ́ orísun ìyè fún àwọn tí ó ní i, ṣùgbọ́n ìwà òmùgọ̀ ń kó ìyà jẹ aláìgbọ́n.
Pín
Owe 16BMYOOwe 16:22YCE(Yoruba Bible)
Orísun ìyè ni ọgbọ́n jẹ́ fún àwọn tí wọn ní i, agọ̀ sì jẹ́ ìjìyà fún àwọn òmùgọ̀.
Pín
Owe 16YCE