Owe 24:33-34
Owe 24:33-34 Bibeli Mimọ (YBCV)
Orun diẹ si i, õgbe diẹ, ikawọkòpọ lati sùn diẹ. Bẹ̃li òṣi rẹ yio de bi ẹniti nrìn; ati aini rẹ bi ọkunrin ti o hamọra ogun.
Pín
Kà Owe 24Orun diẹ si i, õgbe diẹ, ikawọkòpọ lati sùn diẹ. Bẹ̃li òṣi rẹ yio de bi ẹniti nrìn; ati aini rẹ bi ọkunrin ti o hamọra ogun.