Owe 28:1 - Compare All Versions
Owe 28:1 YBCV (Bibeli Mimọ)
ENIA buburu sá nigbati ẹnikan kò le e: ṣugbọn olododo laiya bi kiniun.
Pín
Owe 28 YBCVOwe 28:1 YCE (Yoruba Bible)
Àwọn eniyan burúkú a máa sá, nígbà tí ẹnikẹ́ni kò lé wọn, ṣugbọn olódodo a máa láyà bíi kinniun.
Pín
Owe 28 YCEOwe 28:1 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ènìyàn búburú ń sá bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹnìkan kò lé e ṣùgbọ́n olódodo láyà bí i kìnnìún.
Pín
Owe 28 BMYO